Strait of Hurmuz


Strait of Hormuz ( /hɔrˈmuːz/)[lower-alpha 1] jẹ́ ọ̀nà omi tóóró láàárín Persian Gulf àti Gulf of Oman. Orílẹ̀-èdè Iran wà ẹ̀bádò rẹ̀ lápá àríwá, tí Musandam Peninsula lábẹ́ ìjọba Musandam Governorate ti Oman wà lápá gúúsù ẹ̀bádò rẹ̀, tí apá ka erékùṣù-nílẹ̀ tí orílẹ̀-èdè United Arab Emirates wà lápá gúúsù ìwọ̀-oòrùn rẹ̀. The strait is about Tóóró omi náà tó 104 miles (90 nmi; 167 km) ní gúngún, tí fífẹ̀ rẹ̀ yàtọ̀ níwọ̀n bí i Àdàkọ:Cvt sí Àdàkọ:Cvt.[1][2]
Ó jẹ́ ọ̀nà omi òkun kan ṣoṣo láti Persian Gulf sí orí ọ̀sà gbalasa, tí ó sì tún jẹ́ ọ̀nà àgbáyé kan pàtàkì sí choke points.[3] Lọ́dún 2023–2025, ìdá ogún (20%) afẹ́fẹ́ gáàsì àgbáyé, (liquefied natural gas) (LNG) àti ìdá mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25%) tí seaborne oil trade passed through the strait annually. It is a major source of petroleum products for Europe and Asia and has been described as "critical" to Europe's energy security.[4] Bẹ́ẹ̀ náà ló tún jẹ́ ọ̀nà omi fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè Gulf tí UAE, Qatar, Kuwait àti Bahrain wà lára wọn, bẹ́ẹ̀ náà ìjàmbá sí ọ̀nà omi tóóró náà lè ṣàkóbá fún ìlọgeere ọjà.[5]
The strait has traditionally never been closed for extended time during Middle East conflicts (unlike the Straits of Tiran/Bab-el-Mandeb)[6] though Iran occasionally had threatened to close the strait,[7][8] and preparations to mine it have been undertaken.[9] The strait has become a major focus during the 2026 Iran war, resulting in the Strait of Hormuz crisis.[10]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Jon M. Van Dyke (2 October 2008). "Transit Passage Through International Straits". The Future of Ocean Regime-Building. University of Hawaii. p. 216. doi:10.1163/ej.9789004172678.i-786.50. ISBN 9789004172678. Archived from the original on 7 August 2020. https://www.law.hawaii.edu/sites/www.law.hawaii.edu/files/content/Faculty/Straits100308.pdf. Retrieved 6 July 2019.
- ↑ "The Strait of Hormuz is the world's most important oil transit chokepoint". U.S. Energy Information Administration. 4 January 2012. Archived from the original on 11 September 2018. Retrieved 11 September 2018. Unknown parameter
|url-status=ignored (help) - ↑ Viktor Katona. "How Iran Plans To Bypass The World's Main Oil Chokepoint". Oilprice.com. Archived from the original on 11 September 2018. Retrieved 11 September 2018. Unknown parameter
|url-status=ignored (help) - ↑ "Why is the Strait of Hormuz critical to Europe?". euronews (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 16 March 2026. Retrieved 18 March 2026.
- ↑ Surucu-Balci, Ebru; Balci, Gokcay (4 March 2026). "Strait of Hormuz: Gulf states' food security is at immediate risk but wider shortages could push up consumer prices globally". The Conversation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 18 March 2026.
- ↑ "Oil Prices Jump, But Middle East Oil Keeps Flowing Uninterrupted". OilPrice.com. 17 June 2025.
the narrow lane has never been blocked in any previous conflict in the Middle East.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>tag; no text was provided for refs named "auto". - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>tag; no text was provided for refs named ":4". - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>tag; no text was provided for refs named ":3". - ↑ Sinha, Aditya (25 February 2026). "Why Hormuz, not Fordow, is the real centre of gravity in the Iran crisis". First Post. Retrieved 18 March 2026.
<ref> tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/> tag was found.