Niger (country)
République du Niger Republic of Niger | |
|---|---|
Motto: "Fraternité, Travail, Progrès" (Faransé) "Fraternity, Work, Progress" | |
Orin ìyìn: La Nigérienne | |
| Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Niamey |
| Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Faransé (Official) Haúsá, Fulfulde, Gulmancema, Kanuri, Zarma, Tamasheq (as "national") |
| Orúkọ aráàlú | Nigerien; Nigerois |
| Ìjọba | Military Junta |
| Mohamed Bazoum | |
| Ouhoumoudou Mahamadou | |
| Ilominira from France | |
• Declared | August 3, 1960 |
| Ìtóbi | |
• Total | 1,267,000 km2 (489,000 sq mi) (22nd) |
• Omi (%) | 0.02 |
| Alábùgbé | |
• July 2008[1] estimate | 13,272,679 |
• Ìdìmọ́ra | 10.48/km2 (27.1/sq mi) |
| GDP (PPP) | 2008 estimate |
• Total | $10.164 billion[2] |
• Per capita | $738[2] |
| GDP (nominal) | 2008 estimate |
• Total | $5.379 billion[2] |
• Per capita | $391[2] |
| Gini (1995) | 50.5 high |
| HDI (2007) | ▲ 0.374 Error: Invalid HDI value · 174th |
| Owóníná | West African CFA franc (XOF) |
| Ibi àkókò | UTC+1 (WAT) |
| UTC+1 (not observed) | |
| Ojúọ̀nà ọkọ́ | otun[3] |
| Àmì tẹlifóònù | 227 |
| ISO 3166 code | NE |
| Internet TLD | .ne |
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ti Nàìjá (Republic of the Niger) jẹ́ orílẹ̀-èdè tí kò ní etíkun ní Ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà. Ó jẹ́ orílẹ̀-èdè aláṣẹ kan ṣoṣo (unitary state). Ó ní ààlà pẹ̀lú Libya ní ìhà àríwá ìlà-oòrùn, Chad ní ìhà ìlà-oòrùn, Nàìjíríà ní gúúsù, Benin àti Burkina Faso ní gúúsù ìwọ̀ oòrùn, Mali ní ìwọ̀ oòrùn, àti Algeria ní àríwá ìwọ̀ oòrùn.Agbègbè ilẹ̀ rẹ̀ tó fẹrẹ̀ jẹ́ 1.27 mílíọ̀nù kìlómítà onígun mẹ́rin (km²), èyí sì mú un jẹ́ orílẹ̀-èdè kẹfà tó tóbi jù lọ ní Áfíríkà. Ó tún jẹ́ orílẹ̀-èdè tí kò ní etíkun tó tóbi jù lọ ní Ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà, àti ẹlẹ́ẹ̀kejì tó tóbi jù lọ lára àwọn orílẹ̀-èdè tí kò ní etíkun ní Áfíríkà, lẹ́yìn Chad.Ju 80% ilẹ̀ Nàìjá lọ wà lábẹ́ Aṣálẹ̀ Sahara. Àwọn olùgbé rẹ̀, tí ọ̀pọ̀ jù lọ jẹ́ ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí, tó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ mílíọ̀nù 25, ń gbé ní pàtàkì ní gúúsù àti ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè náà.Olú-ìlú Nàìjá ni Niamey, ó sì wà ní igun gúúsù ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè náà, lẹ́gbẹ̀ẹ́ Odò Niger, èyí tí orílẹ̀-èdè náà ti gba orúkọ rẹ̀.
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "CIA World Factbook 2008". Archived from the original on 2020-06-08. Retrieved 2009-08-07.
- 1 2 3 4 "Niger". International Monetary Fund. Retrieved 2009-04-22.
- ↑ Which side of the road do they drive on? Brian Lucas. August 2005. Retrieved 2009-01-28